ILE IWOSAN ORUNMILA MIMO IBA ORIKI MORNING MORNING PRAYER TO OLODUMARE, IFA, IRUNMALE, EGUNGUN ILE
IBA HOMAGE Iba O Homage to Olodumare Olodumare Oba ajiki Olodumare, Divine Ruler who must be reverently praised every morning (unmovable, unchanging) Edumare Oba a ji ge Edumare (Orunmila), the most respected with adoration, Ogege Oba tiin gbele aye gun The pivot of life equilibrium Ogbagba nla Oba tolode-Orun The grand commander of the cosmic zone Iba O Homage to Ati yo ojo The rising of the Sun Ati wo oorun The setting of the Sun Iba kutukutu awo owuro Kutukutu, the priest of the early Dawn Ganrin Ganrin Awo osan gangan Ganrin Ganrin , priest of the Noon Winrin winrin Awo Oru Winrin winrin, priest of the Night
1
Ati okuku-su-wii, Awo Oganjo Okuku-su-wi, priest of the mid-night Iba Oriki Morning Prayer Iba Elewu ide, Homage to Elewu Ide, Orisa of the Sun Iba Elewu Ala, Homage to Elewu Ala, Orisa of the Moon Iba Irawo-sasa n be lehin f osupa Homage to Irawo-sasa, Orisa of the cosmic stars, Afefelegelege Awo Isalu aye Afefelegelege, priest of the Earth Efuufulegelege Awo isalu orun Efuufulegelege, priest of the Universe Iba Ajagunmole Oluwo ode Orun Homage to Ajagunmole, priest of the great beyond Iba Aromoganyin Onibode aye oun orun Homage to Aromoganyin, the gateman of the great beyond Iba Awonamaja Babalawo tii n komo nifa oju orun Homage to Awonamaja, Ifa priest that teaches Ifa in our dreams Iba Esu lalu-okiri-oko, Kiri-ogo Homage to Esu lalu-okiri-oko, Kiri-ogo Iba Eyin Iyami Homage to Eyin (It is you I am calling please) Iyami Afinju eye tii n je loju oloko The skillful bird that feed in the presence of the owner Afinju eye tii ni fiye sap tii n fiko sehin The skillful bird with feathers and beak Afinju eye tii n fiye sapa tii n f'eekun sehin The skillful bird with feathers and teeth Afinju eye tii n fiye sapa tii n fehin sehin
2
The skillful bird with bones as feathers and bones as teeth Afinju eye tii n fegungun sapa tii n fegungun sehin The skillful bird with iron feathers and iron teeth Afinju eye tii n firin n sapa tii n firin sehin The skillful bird with feathers of fire and teeth of fire Iba Oriki Morning Prayer Iba Ile, Otete, lanbua, Homage to The Mother Earth Aterere kari aye The special carpet of the Universe Agbohun, maa for, abiyamo tooto The Mute listener, Mother of All Iba Ifa on Olodumare Homage to Ifa the voice of the Almighty God Iba Orunmila Eleri Ipin Homage to Orunmila witness of destiny Atori eni tio sunwon se, The one that changes misfortune to fortune Iba Aboru, Aboye, Abosise Homage to the sacrifice that is given, the sacrifice that is accepted, the sacrifice that has manifested Iba Ogun, yankan bi ogbe, Homage to Ogun the bleeding of the flesh wound Iba otarigidi-tii n se yeye Ogun Homage to Otarigidi-tii Ogun's God-mother Iba omobowu oun ewiri-maje Homage to Omobowu and Ewiri-maje, Ogun's wives Iba Ija Iba Osoosi Homage to Osoosi Iba Olutasin tokotoko bo Ogun Olutasin, the first to appease Ogun Iba Ope ti a n tidi n be tii n tori gbe ni
3
Homage to the Palm Tree that is appease at the base, that bring forth benefiting fruits at the top Iba Ope to fidi sekan to fori se pupo Homage to the Palm tree with one trunk but many branches Iba Egbe Oga-Ogo Homage to Egbe the cosmic companions
Iba Oriki Morning Prayer Iba Ogba Homage to Ogba, the astral friends Iba Olunkori-Orisa ewe Homage to Olunkori, The Orisa of children astral mates Iba Sango, Oluorojo, bambi-arigba ota segun Homage to Sango, Oluorojo, Bambi, the Orisa of Thunder with many thunderbolts Iba Haawa, Iba Gambe-Olu, Homage to Haawo and Gambe-Olu wives of Sango Iba Oya Oriri, Obinrin gbongbonran tii n yoko re loko ebu Homage to Oya Oriri, the powerful woman that recused her husband from ridicules, Iba Oke ganga, Oke ganga Homage to Oke ganga, Oke ganga Iba Aganju Homage to Orisa Aganju Iba Mojelewu Homage to Orisa Mojelewu Iba Okeere Homage to Orisa Okeere Iba Yemoja, Iba odo Ogun Homage to Orisa Yemoja and river Ogun Iba Osaara, Iba Toorosi
4
Homage to Osaara and Toorosi, Sango's Godmothers Iba Iyalode lode oro Homage to Iyalode, the custodian of Oro (Oro town) Iba Moremi lode Ofa Homage to Moremi custodian of Ofa (Ofa town) Iba Oba Homage to Orisa Oba the faithful and committed wife of Sango, Iba O, Obatala, Oba taasa Homage to Obatala King of Orisa Oba Taasa Iba Oriki Morning Prayer Oba Patapata lode Iranje, King of Orisa, the custodian of Iranje (Iranje town) Iba Iranje ile, Iba Iranje Oko, Iba Ifon-Osun Homage to Iranje ile, Iranje Oko, Ifon Osun (all towns) Iba Igbin, Iba Igbin-Oosa Homage to the snail and the Obatala's drum Iba Alagemo-teerekange Homage to Alagemo-teerekange, the chameleon Je a gbo Je a to We are wishing for longevity Iba Abomoda omo Oosa-Agbowujin Homage to Abamoda, the child of Oosa-Agbowujin (plant bryophillum pinnatum) Mo daba ire aiku, ire aje, ire aya/oko, ire omo, ire Isegun, ire gbogbo We are wishing for all good fortune Aba ti Alagemo bada l Oosa-Oke n gba It is the good wishes of Alagemo that Orisa Accepts Iba gunyan gunyan ile Ido Homage to the Gunyan gunyan women of Ile Ido (Ido Town) Iba rokaroka Obinrin Ibadan Homage to the Rokaroka women of Ibadan (Ibadan Town)
5
Iba Aje tii n somo Olu-Ibini Homage to Aje, princess of Ibini Iba Okun tii n somo Ode Irada Homage to Okun, the princess of Irada (Irada town) Iba Oro, Oropoto pomupomu Homage to Oro Oropoto pomupomu Tobi omo lewelewe ti kan kan o sofun The Orisa with many surviving children Iba Osanyin-mogboraye Homage to Osanyin-mogboraye To gba opa lowo Olokunrun sanu The Healer of the sick Iba Olokun Homage to Orisa Olokun of the ocean Iba Oriki Morning Prayer Iba Olosa Homage to Orisa Olosa of the lagoon Iba Odu loogbo-oje Homage to Orisa Odu loogbo-oje Iba Osun Awura-Olu Homage to Orisa Osun, owner of the beaded comb Olooya-Iyun, Awede koto wemo She cleansed her brass and later bathes her children Iba Iyami Osoronga lode Ipokia Homage to Iyami Osoronga custodian of Ipokia (Ipokia town) Iba Ori-eni Homage to ones Destiny Iba Ikin-eni Homage to one's Ikin (Sacred Palm Kernels), all ancestral male Orisa and ancestral female Orisa Iba Yeye Homage to One's Mother Iba Baba Homage to One's Father Iba Araba Agbaye of Ile Ife Awoyemi Aworeni Mokanranwale Adisa
6
Homage to the Araba of the World located in Ile Ife, Nigeria Awoyemi Aworeni Mokanranwale Adisa Iba Oluwo Homage to One's Spiritual Teacher Iba Ojugbona Homage to One's chief officiating priest Iba Iparipa adaso-mamuro Homage to the insect communities Iba Eyin Isoro-Orun Homage to Isoro-Orun the Astral Ancestral Orisa Iba ara Ile Homage to all spiritual houses in the world Awa juba kee je kiba we se, Ase! We sincerely pay our homage, Accept our homage with Understanding, Wisdom, and Kindness, May it be so
7